Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 23:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn bi iwọ o ba gbà ohùn rẹ̀ gbọ́ nitõtọ, ti iwọ si ṣe gbogbo eyiti mo wi; njẹ emi o jasi ọtá awọn ẹniti nṣe ọtá nyin, emi o si foró awọn ti nforó nyin.

Ka pipe ipin Eks 23

Wo Eks 23:22 ni o tọ