Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 2:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati Farao si gbọ́ ọ̀ran yi, o nwá ọ̀na lati pa Mose. Ṣugbọn Mose sá kuro niwaju Farao, o si ngbé ilẹ Midiani: o si joko li ẹba kanga kan.

Ka pipe ipin Eks 2

Wo Eks 2:15 ni o tọ