Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 2:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si wipe, Tali o fi ọ jẹ́ olori ati onidajọ lori wa? iwọ fẹ́ pa mi bi o ti pa ara Egipti? Mose si bẹ̀ru, o si wipe, Lõtọ ọ̀ran yi di mimọ̀.

Ka pipe ipin Eks 2

Wo Eks 2:14 ni o tọ