Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 18:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki nwọn ki o si ma ṣe idajọ awọn enia nigbakugba: yio si ṣe, gbogbo ẹjọ́ nla ni ki nwọn ki o ma mú tọ̀ ọ wá, ṣugbọn gbogbo ẹjọ́ kekeké ni ki nwọn ki o ma dá: yio si rọrùn fun iwọ tikalarẹ, nwọn o si ma bá ọ rù ẹrù na.

Ka pipe ipin Eks 18

Wo Eks 18:22 ni o tọ