Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 18:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Pẹlupẹlu iwọ o si ṣà ninu gbogbo awọn enia yi awọn ọkunrin ti o to, ti o bẹ̀ru Ọlọrun, awọn ọkunrin olõtọ, ti o korira ojukokoro; irú awọn wọnni ni ki o fi jẹ́ olori wọn, lati ṣe olori ẹgbẹgbẹrun, ati olori ọrọrún, ati olori arãdọta, ati olori mẹwamẹwa.

Ka pipe ipin Eks 18

Wo Eks 18:21 ni o tọ