Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 17:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kiyesi i, emi o duro niwaju rẹ nibẹ̀ lori okuta ni Horebu; iwọ o si lù okuta na, omi yio si jade ninu rẹ̀, ki awọn enia ki o le mu. Mose si ṣe bẹ̃ li oju awọn àgbagba Israeli.

Ka pipe ipin Eks 17

Wo Eks 17:6 ni o tọ