Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 17:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si wi fun Mose pe, Kọja lọ siwaju awọn enia na, ki o si mú ninu awọn àgbagba Israeli pẹlu rẹ, ki o si mú ọpá rẹ, ti o fi lù odò nì li ọwọ́ rẹ, ki o si ma lọ.

Ka pipe ipin Eks 17

Wo Eks 17:5 ni o tọ