Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 15:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA li agbara ati orin mi, on li o si di ìgbala mi: eyi li Ọlọrun mi, emi o si fi ìyin fun u; Ọlọrun baba mi, emi o gbé e leke.

Ka pipe ipin Eks 15

Wo Eks 15:2 ni o tọ