Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 15:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

NIGBANA ni Mose ati awọn ọmọ Israeli kọ orin yi si OLUWA nwọn si wipe, Emi o kọrin si OLUWA, nitoriti o pọ̀ li ogo: ati ẹṣin ati ẹlẹṣin on li o bì ṣubu sinu okun.

Ka pipe ipin Eks 15

Wo Eks 15:1 ni o tọ