Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 12:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi awọn ara ile na ba si kere jù ìwọn ọdọ-agutan na lọ, ki on ati aladugbo rẹ̀ ti o sunmọ-eti ile rẹ̀, ki o mú gẹgẹ bi iye awọn ọkàn na, olukuluku ni ìwọn ijẹ rẹ̀ ni ki ẹ ṣiro ọdọ-agutan na.

Ka pipe ipin Eks 12

Wo Eks 12:4 ni o tọ