Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 12:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si pè Mose on Aaroni li oru, o si wipe, Ẹ dide, ki ẹ jade lọ kuro lãrin awọn enia mi, ati ẹnyin ati awọn ọmọ Israeli; ki ẹ si lọ sìn OLUWA, bi ẹ ti wi.

Ka pipe ipin Eks 12

Wo Eks 12:31 ni o tọ