Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 12:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Farao si dide li oru, on ati gbogbo awọn iranṣẹ rẹ̀, ati awọn ara Egipti; igbe nla si ta ni Egipti; nitoriti kò si ile kan ti enia kan kò kú.

Ka pipe ipin Eks 12

Wo Eks 12:30 ni o tọ