Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 12:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoriti OLUWA yio kọja lati kọlù awọn ara Egipti; nigbati o ba si ri ẹ̀jẹ lara atẹrigba, ati lara opó ìha mejeji, OLUWA yio si rekọja ẹnu-ọ̀na na, ki yio jẹ ki apanirun ki o wọle nyin wá lati kọlù nyin.

Ka pipe ipin Eks 12

Wo Eks 12:23 ni o tọ