Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 12:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin o si mú ìdi ewe-hissopu, ẹ o si fi bọ̀ ẹ̀jẹ ti o wà ninu awokoto, ẹ o si fi ẹ̀jẹ na ti o wà ninu awokoto kùn ara atẹrigba, ati opó ìha mejeji; ẹnikẹni ninu nyin kò si gbọdọ jade lati ẹnu-ọ̀na ile rẹ̀ titi yio fi di owurọ̀.

Ka pipe ipin Eks 12

Wo Eks 12:22 ni o tọ