Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹk. Jer 1:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jerusalemu ti da ẹ̀ṣẹ gidigidi, nitorina li o ṣe di ẹni-irira: gbogbo awọn ti mbu ọla fun u kẹgan rẹ̀, nitoripe nwọn ri ihoho rẹ̀: lõtọ on kẹdùn, o si yi ẹ̀hin pada.

Ka pipe ipin Ẹk. Jer 1

Wo Ẹk. Jer 1:8 ni o tọ