Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dan 9:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Adọrin ọ̀sẹ li a pinnu sori awọn enia rẹ, ati sori ilu mimọ́ rẹ, lati ṣe ipari irekọja, ati lati fi edidi di ẹ̀ṣẹ, ati lati ṣe ilaja fun aiṣedẽde ati lati mu ododo ainipẹkun wá ati lati ṣe edidi iran ati woli, ati lati fi ororo yàn Ẹni-mimọ́ julọ nì.

Ka pipe ipin Dan 9

Wo Dan 9:24 ni o tọ