Li akokò ikẹhin ijọba wọn, nigbati awọn oluṣe irekọja ba de ni kíkun, li ọba kan yio dide, ti oju rẹ̀ buru, ti o si moye ọ̀rọ arekereke.