Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dan 7:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi o ṣe ti awọn ẹranko iyokù ni, a ti gba agbara wọn kuro: nitori a ti yàn akokò ati ìgba fun wọn bi olukulùku yio ti pẹ tó.

Ka pipe ipin Dan 7

Wo Dan 7:12 ni o tọ