Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dan 4:37 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nisisiyi, emi Nebukadnessari yìn, mo si gbé Ọba ọrun ga, mo si fi ọlá fun u, ẹniti gbogbo iṣẹ rẹ̀ iṣe otitọ, ati gbogbo ọ̀na rẹ̀ iṣe idajọ: ati awọn ti nrìn ninu igberaga, on le rẹ̀ wọn silẹ.

Ka pipe ipin Dan 4

Wo Dan 4:37 ni o tọ