Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dan 4:36 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lakoko kanna oye mi pada tọ̀ mi wá; ati niti ogo ijọba mi, ọlá ati ogo didan mi si pada wá sọdọ mi: awọn ìgbimọ ati awọn ijoye mi si ṣafẹri mi; a si fi ẹsẹ mi mulẹ ninu ijọba mi, emi si ni ọlanla agbara jù ti iṣaju lọ.

Ka pipe ipin Dan 4

Wo Dan 4:36 ni o tọ