Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dan 4:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eyi ti ewe rẹ̀ lẹwà, ti eso rẹ̀ si pọ̀, ninu eyi ti onjẹ si wà fun gbogbo ẹda, labẹ eyi ti awọn ẹranko igbẹ ngbe, lori ẹka eyi ti awọn ẹiyẹ oju-ọrun ni ibugbe wọn.

Ka pipe ipin Dan 4

Wo Dan 4:21 ni o tọ