Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

A. Oni 20:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo awọn ọkunrin Israeli si dide kuro ni ipò wọn, nwọn si tẹ́gun ni Baali-tamari: awọn ti o wà ni ibuba ninu awọn enia Israeli si dide kuro ni ipo wọn, lati pápa Gibea wá.

Ka pipe ipin A. Oni 20

Wo A. Oni 20:33 ni o tọ