Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

A. Oni 20:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ Benjamini si wipe, A lù wọn bolẹ niwaju wa, gẹgẹ bi ìgba iṣaju. Ṣugbọn awọn ọmọ Israeli wipe, Ẹ jẹ ki a sá, ki a si fà wọn kuro ni ìlú si opópo.

Ka pipe ipin A. Oni 20

Wo A. Oni 20:32 ni o tọ