Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

A. Oni 18:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ Dani si rán ọkunrin marun ninu idile wọn lati àgbegbe wọn wá, awọn ọkunrin alagbara, lati Sora, ati Eṣtaolu lọ, lati lọ ṣe amí ilẹ na, ati lati rìn i wò; nwọn si wi fun wọn pe, Ẹ lọ rìn ilẹ na wò: nwọn si dé ilẹ òke Efraimu, si ile Mika, nwọn si wọ̀ nibẹ̀.

Ka pipe ipin A. Oni 18

Wo A. Oni 18:2 ni o tọ