Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

A. Oni 18:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

LI ọjọ́ wọnni ọba kan kò sí ni Israeli: ati li ọjọ́ wọnni ẹ̀ya Dani nwá ilẹ-iní kan lati joko si; nitoripe titi o fi di ọjọ́ na, ilẹ-iní wọn lãrin awọn ẹ̀ya Israeli kò ti ibọ́ si ọwọ́ wọn.

Ka pipe ipin A. Oni 18

Wo A. Oni 18:1 ni o tọ