Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Timoti Kinni 6:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí wọ́n wà lábẹ́ àjàgà ẹrú níláti rí i pé wọ́n ń bu ọlá fún àwọn ọ̀gá wọn ní ọ̀nà gbogbo, kí àwọn eniyan má baà sọ̀rọ̀ ìṣáátá sí orúkọ Ọlọrun ati ẹ̀kọ́ onigbagbọ.

Ka pipe ipin Timoti Kinni 6

Wo Timoti Kinni 6:1 ni o tọ