Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Timoti Kinni 3:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò gbọdọ̀ jẹ́ ọ̀mùtí, tabi ẹni tí máa ń lu eniyan. Ṣugbọn kí ó jẹ́ onífaradà. Kò gbọdọ̀ jẹ́ alásọ̀, tabi ẹni tí ó ní ọ̀kánjúwà owó.

Ka pipe ipin Timoti Kinni 3

Wo Timoti Kinni 3:3 ni o tọ