Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Timoti Kinni 3:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, olùdarí níláti jẹ́ ẹni tí kò lẹ́gàn; kò gbọdọ̀ ní ju iyawo kan lọ, ó gbọdọ̀ jẹ́ eniyan jẹ́jẹ́, ọlọ́gbọ́n eniyan, ọmọlúwàbí, ẹni tí ó fẹ́ràn láti máa ṣe eniyan lálejò, tí ó sì fẹ́ràn iṣẹ́ olùkọ́ni.

Ka pipe ipin Timoti Kinni 3

Wo Timoti Kinni 3:2 ni o tọ