Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Timoti Kinni 3:15 BIBELI MIMỌ (BM)

nítorí bí mo bá pẹ́ kí n tó wá, kí o lè mọ̀ bí ó ti yẹ láti darí ètò ilé Ọlọrun, èyí tíí ṣe ìjọ Ọlọrun alààyè, òpó ati ààbò òtítọ́.

Ka pipe ipin Timoti Kinni 3

Wo Timoti Kinni 3:15 ni o tọ