Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Timoti Kinni 2:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Bákan náà, kí àwọn obinrin wọ aṣọ bí ó ti yẹ, aṣọ tí kò ní ti eniyan lójú, kí wọ́n ṣe ara wọn lọ́ṣọ̀ọ́ níwọ̀ntúnwọ̀nsì. Kí wọn má ṣe di irun wọn ní aláràbarà fún àṣehàn. Kí wọn má ṣe kó ohun ọ̀ṣọ́ bíi wúrà ati ìlẹ̀kẹ̀ tabi aṣọ olówó ńlá sára.

Ka pipe ipin Timoti Kinni 2

Wo Timoti Kinni 2:9 ni o tọ