Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Timoti Kinni 2:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà mo fẹ́ kí gbogbo eniyan máa gbadura ninu gbogbo ìsìn, kí wọn máa gbé ọwọ́ adura sókè pẹlu ọkàn kan, láìsí èrò ibinu tabi ọkàn àríyànjiyàn.

Ka pipe ipin Timoti Kinni 2

Wo Timoti Kinni 2:8 ni o tọ