Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Timoti Kinni 1:4 BIBELI MIMỌ (BM)

kí wọn má jókòó ti àwọn ìtàn tí kò lẹ́sẹ̀ nílẹ̀ ati ìtàn ìrandíran tí kò lópin, tí ó máa ń mú àríyànjiyàn wá, dípò ẹ̀kọ́ nípa Ọlọrun tí a mọ̀ nípa igbagbọ.

Ka pipe ipin Timoti Kinni 1

Wo Timoti Kinni 1:4 ni o tọ