Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Timoti Kinni 1:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí mò ń lọ sí Masedonia, mo gbà ọ́ níyànjú pé kí o dúró ní Efesu, kí o pàṣẹ fún àwọn kan kí wọn má ṣe kọ́ eniyan ní ẹ̀kọ́ tí ń ṣini lọ́nà,

Ka pipe ipin Timoti Kinni 1

Wo Timoti Kinni 1:3 ni o tọ