Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Timoti Kinni 1:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Irú àwọn bẹ́ẹ̀ ní Himeneu ati Alẹkisanderu, àwọn tí mo ti fà lé Satani lọ́wọ́ kí ó lè bá wọn wí kí wọn má ṣe sọ̀rọ̀ àbùkù mọ́.

Ka pipe ipin Timoti Kinni 1

Wo Timoti Kinni 1:20 ni o tọ