Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Timoti Kinni 1:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìdí tí ó fi ṣàánú mi nìyí, pé èmi ni Kristi Jesu kọ́kọ́ yọ́nú sí ju ẹnikẹ́ni lọ. Mo wá di àpẹẹrẹ gbogbo àwọn tí wọn yóo gbà á gbọ́ tí wọn yóo sì ní ìyè ainipẹkun.

Ka pipe ipin Timoti Kinni 1

Wo Timoti Kinni 1:16 ni o tọ