Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Timoti Kinni 1:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ yìí: ó dájú, ó sì yẹ ní gbígbà tọkàntọkàn, pé Kristi Jesu wá sinu ayé láti gba ẹlẹ́ṣẹ̀ là. Èmi yìí sì ni olórí àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀.

Ka pipe ipin Timoti Kinni 1

Wo Timoti Kinni 1:15 ni o tọ