Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Timoti Keji 4:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Àkókò ń bọ̀ tí àwọn eniyan kò ní fẹ́ fetí sí ẹ̀kọ́ tí ó yè. Ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ti ara wọn ni wọn yóo tẹ̀lé, tí wọn yóo kó àwọn olùkọ́ tira, tí wọn yóo máa sọ ohun tí wọn máa ń fẹ́ gbọ́ fún wọn.

Ka pipe ipin Timoti Keji 4

Wo Timoti Keji 4:3 ni o tọ