Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Timoti Keji 4:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Waasu ọ̀rọ̀ náà. Tẹnumọ́ ọn ní àkókò tí ó wọ̀ ati àkókò tí kò wọ̀. Máa báni wí. Máa gbani ní ìyànjú. Máa gbani ní ìmọ̀ràn, pẹlu ọpọlọpọ sùúrù tí ó yẹ kí ẹni tí yóo bá kọ́ eniyan lẹ́kọ̀ọ́ dáradára ní.

Ka pipe ipin Timoti Keji 4

Wo Timoti Keji 4:2 ni o tọ