Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Tẹsalonika Kinni 4:17 BIBELI MIMỌ (BM)

A óo wá gbé àwa tí ó kù lẹ́yìn, tí a wà láàyè, lọ pẹlu wọn ninu awọsanma, láti lọ pàdé Oluwa ní òfuurufú, a óo sì máa wà lọ́dọ̀ Oluwa laelae.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Kinni 4

Wo Tẹsalonika Kinni 4:17 ni o tọ