Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Tẹsalonika Kinni 4:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí nígbà tí ohùn àṣẹ bá dún, Olórí àwọn angẹli yóo fọhùn, fèrè Ọlọrun yóo dún, Oluwa fúnrarẹ̀ yóo sọ̀kalẹ̀ láti ọ̀run. Àwọn òkú ninu Jesu ni yóo kọ́kọ́ jinde.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Kinni 4

Wo Tẹsalonika Kinni 4:16 ni o tọ