Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Tẹsalonika Kinni 4:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ gbìyànjú láti fi ọkàn yín balẹ̀. Ẹ má máa yọjú sí nǹkan oní-ǹkan. Ẹ tẹpá mọ́ṣẹ́, gẹ́gẹ́ bí a ti sọ fun yín.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Kinni 4

Wo Tẹsalonika Kinni 4:11 ni o tọ