Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Tẹsalonika Kinni 4:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ gan-an ni ẹ sì ń ṣe sí gbogbo àwọn onigbagbọ ní gbogbo Masedonia. Ẹ̀yin ará, mò ń rọ̀ yín, ẹ túbọ̀ máa ṣe bẹ́ẹ̀ ati jù bẹ́ẹ̀ lọ.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Kinni 4

Wo Tẹsalonika Kinni 4:10 ni o tọ