Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 8:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí àwọn tí ó ń hùwà gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ẹran- ara ń lò a máa lépa ìtẹ́lọ́rùn fún ẹran-ara; ṣugbọn àwọn tí Ẹ̀mí ń darí a máa lépa àwọn nǹkan ti Ẹ̀mí.

Ka pipe ipin Romu 8

Wo Romu 8:5 ni o tọ