Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 8:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun ṣe èyí kí á lè tẹ̀lé ìlànà Òfin ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́, àní àwa tí ìhùwàsí wa kì í ṣe bíi tí ẹni tí ẹran-ara ń lò ṣugbọn bí àwọn ẹni tí Ẹ̀mí ń darí.

Ka pipe ipin Romu 8

Wo Romu 8:4 ni o tọ