Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 3:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ní àkókò yìí, ọ̀nà tí Ọlọrun fi ń dá eniyan láre ti hàn láìsí Òfin, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àkọsílẹ̀ ti Òfin ati ti àwọn wolii Ọlọrun jẹ́rìí sí i.

Ka pipe ipin Romu 3

Wo Romu 3:21 ni o tọ