Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 3:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí gẹ́gẹ́ bí ó ti wà ní àkọsílẹ̀, bí a bá mú Òfin tí a fi díwọ̀n iṣẹ́ ọmọ eniyan, kò sí ẹ̀dá kan tí a óo dá láre níwájú Ọlọrun. Nítorí òfin níí mú kí eniyan mọ ẹ̀ṣẹ̀ lẹ́ṣẹ̀.

Ka pipe ipin Romu 3

Wo Romu 3:20 ni o tọ