Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 16:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí irú àwọn eniyan bẹ́ẹ̀ kì í ṣe iranṣẹ Oluwa wa Kristi, ikùn ara wọn ni wọ́n ń bọ. Wọn a máa fi ọ̀rọ̀ dídùn ati kí á máa pọ́n eniyan tan àwọn tí kò bá fura jẹ.

Ka pipe ipin Romu 16

Wo Romu 16:18 ni o tọ