Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 15:9 BIBELI MIMỌ (BM)

ati láti jẹ́ kí àwọn tí kò kọlà lè yin Ọlọrun nítorí àánú rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni ó wà ní àkọsílẹ̀ pé,“Nítorí èyí, n óo yìn ọ́ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè,n óo kọrin sí orúkọ rẹ.”

Ka pipe ipin Romu 15

Wo Romu 15:9 ni o tọ