Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 15:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohun tí mò ń sọ ni pé Kristi ti di iranṣẹ fún àwọn tí ó kọlà, láti mú òtítọ́ Ọlọrun ṣẹ, kí ó lè mú àwọn ìlérí tí Ọlọrun ṣe fún àwọn baba-ńlá ṣẹ,

Ka pipe ipin Romu 15

Wo Romu 15:8 ni o tọ