Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 13:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ jẹ́ kí á máa rìn bí ó ti yẹ ní ọ̀sán, kí á má wà ninu àwùjọ aláriwo ati ọ̀mùtí, kí á má máa ṣe ìṣekúṣe, kí á má máa hu ìwà wọ̀bìà, kí á má máa ṣe aáwọ̀. Bẹ́ẹ̀ ni kí á má máa jowú.

Ka pipe ipin Romu 13

Wo Romu 13:13 ni o tọ